101 Languages

Yoruba Word List

The purpose of this list is to give a rough idea of the Yoruba language. The words listed below are not the most common words, but a broad sampling of words. See the Word Lists page for more details.

English

Yoruba
I

émi, mo
you
(singular)

ìwọ, ọ (informal);
ẹ̀yín (formal)
he

ó, òun
we

àwa, a
you
(plural)

ẹ̀yin
they

àwọn
this

eléyí, èyí
that

èyí, èyítí, ohun tí
here

ibí, níhàyín
there

lọhun, nibẹ
who

tani, ẹnití
what

kíni, kínlá, èwo
where

ibo, níbo, níbití
when

ìgbàtí
how

bí, báwo
not

kò, kì
all

gbogbo, olúkúlùkú
many

púpọ̀, pọ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀
some

díẹ, kan, àwọn kan
few

díẹ
other

òmíràn, míràn
one

mení, ọ̀kan
two

méjì
three

mẹta
four

mẹrin
five

màrún
big

nlá, tóbi, gbórin
long

jìnnà, gùn, pẹ́
wide

gbòrò, jìnnà
thick

nípọn
heavy

wúwo
small

kéré, diẹ
short

kúrú
narrow

tóró, híhá, há
thin

tínrín, tẹ́rẹ́ (?)
woman

obìnrin
man
(adult male)

ọkùnrin
man
(human being)

ènìyàn
child
(a youth)

èwe, ọmọ, ọmọdé
wife

ìyàwó, aya
husband

ọkọ
mother

ìyá, abiyamọ
father

bàbá
animal

ẹran
fish

ẹja
bird

ẹiyẹ, ẹyẹ abìyẹ́ (?)
dog

ajá
louse

iná
snake

ejọ́
worm

ekòló, kòkòròìdinaràn
tree

igi
forest

igbó, ẹgàn
stick
(of wood)

kùmọ, ọgọ (?)
fruit

éso, ọmọ
seed

irúgbìn, irúmọ
leaf

ewé
root

gbòngbò, ìpilẹ̀sẹ̀
bark
(of tree)

èpo igi
flower

òdòdó
grass

koríko
rope

okùn
skin
(of a person)

ara
meat
(as in flesh)

ẹran jíjẹ
blood

ẹ̀jẹ
bone

egungun
fat
(noun)

ọ̀rá
egg

ẹyin
horn

ìwo
tail

ìrú
feather
(rather not down)

ìyẹ́ ẹyẹ
hair

irun
head

orí
ear

etí
eye

ojú
nose

imú
mouth

ẹnu
tooth
(rather not molar)

ehín
tongue

ahọ́n
fingernail

èékánná ìka ọwọ́ (?)
foot

ẹsẹ̀
leg

ẹsẹ̀
knee

orúkún, ekún
hand

ọwọ
wing

ìyẹ́ apá
belly

inú, ikùn
guts

ìfun
neck

ọrùn, ẹ̀mí
back

ẹ̀hìn
breast

ọmú, ọyọ̀n
heart

ọkàn
liver

ẹ́dọ
to drink

mu
to eat

jẹ, jẹun
to bite

gé jẹ, bù jẹ
to suck

mu ọmú, fi ẹnu fà mu
to spit

tutọ́
to vomit

bì, pọ̀ jade
to blow
(as wind)

mí kíkanfẹ́ (?)
to breathe

to laugh

rẹrin
to see

rí, fojú rí, ríran
to hear

gbọ, tẹtí sí
to know
(a fact)

mọ̀
to think

rò, ronú, wòye
to smell
(sense odor)

gbórùn
to fear

ẹ̀rù, ìfòyà (?)
to sleep

sùn, simi
to live

wà láyé
to die

kú, ṣaláìsí
to kill

pa, gbẹ̀mí
to fight

ìjà, jagun (?)
to hunt
(transitive)

dẹ, lé, ṣọdẹ
to hit

gbá, nà, lù
to cut

gé, ké, ṣá, yún
to split

là, pín, là wẹ́wẹ́
to stab
(or stick)

gún lọ́bẹ,
fi ohun mímún gún (?)
to scratch
(an itch)

họ, ya, yún,
ya ni nkan
to dig

walẹ̀, wà nílẹ̀, wáàdí
to swim

lúwẹ̀, wẹ̀
to fly

fò, fò-lọ
to walk

rìn, fi ẹsẹ̀ rìn
to come

to lie
(as on one's side)

dùbúlê, nà gbôôrô (?)
to sit

jókó
to stand

dúró, dìde, nàró
to turn
(change direction)

yípadà
to fall
(as in drop)

ṣubú, wó (?)
to give

fi fún, fi bùn, jìn
to hold
(in one's hand)

dìmú, gbámú
to squeeze

fún pọ̀, há láyè
to rub

gbo, pa, fi ra, fi pa
to wash

wẹ̀, fọ̀ bọ́
to wipe

nù, nùkúrò
to pull

to push

tì, tari
to throw

sọ, jù, fi sọ̀kò
to tie

dì, so, se kókó
to sew

rán-ṣọkósọ (?)
to count

kà, rò, ṣírò
to say

wí, sọ
to sing

kọrin
to play

ṣiré
to float

lefó, fó lójú omi
to flow

ṣàn
to freeze

to swell

sun

òrùn
moon

oṣù, òṣùpá
star

ìràwọ̀
water

omi
rain

òjò
river

odò
lake

adágún
sea
(as in ocean)

òkun omi-iyọ́
salt

iyọ̀
stone

òkúta
sand

yanrìn
dust

eruku
earth
(as in soil)

ilẹ̀, erùpẹ̀
cloud

gùdẹ (?)
fog

ìkùúkùù, kùrukùru
sky

ọ̀run, ojú ọ̀run
wind
(as in breeze)

afẹ́fẹ́, ẹ̀fúfú
snow

ìrì dídìòjò dídì (?)
yìnyín ti ohun jábọ́ lójú ọ̀run (?)
ice

yìnyín, omi dídì
smoke

éfí
fire

iná
ash

eérú
to burn
(intransitive)

sún, jóná, mú gbóná
road

ọ̀nà
mountain

òkè gíga
red

pọ́n, pupa (?)
green

aláwọ̀ ewé
yellow

pupa rúsúrúsú bí àwọ ìyeyè (?)
white

funfun
black

aláwọ̀ dúdú, ṣú
night

òru
day
(daytime)

ọjọ́, ọ̀sán
year

ọdún
warm
(as in weather)

gbóná diẹ, lílọ́ wọ́rọ́
cold
(as in weather)

tutù
full

kún
new

[titun]], àkọtun
old

ìdarúgbó, ìdàgbà, gbó, ìhewú
good

rere, suwọ̀n, dára
bad

burú, burúkú, búburú
rotten
(as, a log)

dìbàjẹ́, rà
dirty

léèrí, lẹgbin, àìmọ́, lọ́bùn
straight

tàrà, tọ, láìwọ
round

òbìrìkìtì (?)
sharp
(as a knife)

mímú, yára se kan
dull
(as a knife)

kúnú, àìmú, lọ́ra, kújú, yòpe
smooth

tẹ́jú, tẹ́rẹrẹ, ọ̀bọ̀rọ́
wet

rin, tutu
dry
(adjective)

gbígbẹ, gbẹ, gbẹrẹfu, láìlómi
right
(correct)

títọ́, tó yẹ, dára
near

nítòsí, súnmọ́ra
far

jìnà, jijina
right
(side)

ọ̀tún

View other word lists here